Kol 1:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyiti emi nṣe lãlã ti mo si njijakadi fun pẹlu, gẹgẹ bi iṣẹ agbara rẹ̀, ti nfi agbara ṣiṣẹ gidigidi ninu mi.

Kol 1

Kol 1:20-29