Kol 1:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹ le mã rìn ni yiyẹ niti Oluwa si ìwu gbogbo, ki ẹ ma so eso ninu iṣẹ rere gbogbo, ki ẹ si mã pọ si i ninu ìmọ Ọlọrun;

Kol 1

Kol 1:2-16