Jon 3:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Jona si dide, o si lọ si Ninefe, gẹgẹ bi ọ̀rọ Oluwa. Ninefe si jẹ ilu nla gidigidi tó irin ijọ mẹta.

Jon 3

Jon 3:1-4