Jon 3:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọlọrun si ri iṣe wọn pe nwọn yipada kuro li ọ̀na ibi wọn: Ọlọrun si ronupiwada ibi ti on ti wi pe on o ṣe si wọn; on kò si ṣe e mọ.

Jon 3

Jon 3:4-10