Jon 2:8-10 Yorùbá Bibeli (YCE)

8. Awọn ti nkiyesi eke asan kọ̀ ãnu ara wọn silẹ.

9. Ṣugbọn emi o fi ohùn idupẹ rubọ si ọ; emi o san ẹjẹ́ ti mo ti jẹ. Ti Oluwa ni igbala.

10. Oluwa si sọ fun ẹja na, o si pọ̀ Jona sori ilẹ gbigbẹ.

Jon 2