Jon 2:7-9 Yorùbá Bibeli (YCE)

7. Nigbati o rẹ ọkàn mi ninu mi, emi ranti Oluwa: adura mi si wá sọdọ rẹ sinu tempili mimọ́ rẹ.

8. Awọn ti nkiyesi eke asan kọ̀ ãnu ara wọn silẹ.

9. Ṣugbọn emi o fi ohùn idupẹ rubọ si ọ; emi o san ẹjẹ́ ti mo ti jẹ. Ti Oluwa ni igbala.

Jon 2