Joh 8:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. JESU si lọ si ori òke Olifi.

2. O si tún pada wá si tẹmpili ni kutukutu owurọ̀, gbogbo enia si wá sọdọ rẹ̀; o si joko, o nkọ́ wọn.

Joh 8