Joh 7:22 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori eyi ni Mose fi ìkọlà fun nyin (kì iṣe nitoriti iṣe ti Mose, ṣugbọn ti awọn baba); nitorina ẹ si nkọ enia ni ilà li ọjọ isimi.

Joh 7

Joh 7:21-31