Joh 7:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kikùn pipọ si wà larin awọn ijọ enia nitori rẹ̀: nitori awọn kan wipe, Enia rere ni iṣe: awọn miran wipe, Bẹ̃kọ; ṣugbọn o ntàn enia jẹ ni.

Joh 7

Joh 7:4-21