Joh 4:52 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li o bère wakati ti o bẹ̀rẹ si isàn lọwọ wọn. Nwọn si wi fun u pe, Li ana, ni wakati keje, ni ibà na fi i silẹ.

Joh 4

Joh 4:51-54