Joh 4:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ọpọ awọn ara Samaria lati ilu na wá si gbà a gbọ́, nitori ọ̀rọ obinrin na, o jẹri pe, O sọ gbogbo ohun ti mo ti ṣe fun mi.

Joh 4

Joh 4:32-47