Joh 20:23 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹṣẹ ẹnikẹni ti ẹnyin ba fi jì, a fi ji wọn; ẹ̀ṣẹ ẹnikẹni ti ẹnyin ba da duro, a da wọn duro.

Joh 20

Joh 20:21-26