Joh 2:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NI ijọ kẹta a si nṣe igbeyawo kan ni Kana ti Galili; iya Jesu si mbẹ nibẹ̀:

2. A si pè Jesu ati awọn ọmọ-ẹhin rẹ̀ pẹlu, si ibi igbeyawo.

3. Nigbati waini si tan, iya Jesu wi fun u pe, Nwọn kò ni waini.

Joh 2