Joh 19:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lẹhin na li o si wi fun ọmọ-ẹhin na pe, Wò iya rẹ! Lati wakati na lọ li ọmọ-ẹhin na si ti mu u lọ si ile ara rẹ̀.

Joh 19

Joh 19:22-31