Joh 17:20 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì si iṣe kìki awọn wọnyi ni mo ngbadura fun, ṣugbọn fun awọn pẹlu ti yio gbà mi gbọ́ nipa ọ̀rọ wọn;

Joh 17

Joh 17:14-24