Joh 17:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Tirẹ sá ni gbogbo ohun ti iṣe temi, ati temi si ni gbogbo ohun ti iṣe tirẹ; a si ti ṣe mi logo ninu wọn.

Joh 17

Joh 17:3-17