Joh 12:2 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si se ase-alẹ fun u nibẹ: Marta si nṣe iranṣẹ: ṣugbọn Lasaru jẹ ọkan ninu awọn ti o joko nibi tabili pẹlu rẹ̀.

Joh 12

Joh 12:1-4