Joh 12:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn Farisi wi fun ara wọn pe, Ẹ kiyesi bi ẹ kò ti le bori li ohunkohun? ẹ wò bi gbogbo aiye ti nwọ́ tọ̀ ọ.

Joh 12

Joh 12:10-20