Joh 10:41-42 Yorùbá Bibeli (YCE)

41. Awọn enia pipọ si wá sọdọ rẹ̀, nwọn si wipe, Johanu ko ṣe iṣẹ àmi kan: ṣugbọn otitọ li ohun gbogbo ti Johanu sọ nipa ti ọkunrin yi.

42. Awọn enia pipọ nibẹ̀ si gbà a gbọ́.

Joh 10