Joh 1:45 Yorùbá Bibeli (YCE)

Filippi ri Natanaeli, o si wi fun u pe, Awa ti ri ẹniti Mose ninu ofin ati awọn woli ti kọwe rẹ̀, Jesu ti Nasareti, ọmọ Josefu.

Joh 1

Joh 1:40-47