Joh 1:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si bi i pe, Tani iwọ ha iṣe? Elijah ni ọ bi? O si wipe Bẹ̃kọ. Iwọ ni woli na bi? O si dahùn wipe, Bẹ̃kọ.

Joh 1

Joh 1:13-24