Joh 1:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Eyi si li ẹrí Johanu, nigbati awọn Ju rán awọn alufã ati awọn ọmọ Lefi lati Jerusalemu wá lati bi i lẽre pe, Tani iwọ ṣe?

Joh 1

Joh 1:9-21