Joh 1:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn iye awọn ti o gbà a, awọn li o fi agbara fun lati di ọmọ Ọlọrun, ani awọn na ti o gbà orukọ rẹ̀ gbọ́:

Joh 1

Joh 1:3-14