Joh 1:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. LI àtetekọṣe li Ọ̀rọ wà, Ọ̀rọ si wà pẹlu Ọlọrun, Ọlọrun si li Ọ̀rọ na.

2. On na li o wà li àtetekọṣe pẹlu Ọlọrun.

Joh 1