Joel 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ kede eyi li ãrin awọn keferi; ẹ yà ogun si mimọ́, ẹ ji awọn alagbara, ẹ sunmọ tòsi, ẹ goke wá gbogbo ẹnyin ọkunrin ologun.

Joel 3

Joel 3:1-19