Joel 3:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti ẹnyin ti mu fàdakà mi ati wurà mi, ẹnyin si ti mu ohun rere daradara mi lọ sinu tempili nyin:

Joel 3

Joel 3:1-6