Joel 3:12 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹ ji, ẹ si goke wá si afonifojì Jehoṣafati ẹnyin keferi: nitori nibẹ̀ li emi o joko lati ṣe idajọ awọn keferi yikakiri.

Joel 3

Joel 3:4-16