Joel 2:29 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati pẹlu si ara awọn ọmọ-ọdọ ọkunrin, ati si ara awọn ọmọ-ọdọ obinrin, li emi o tú ẹmi mi jade li ọjọ wọnni.

Joel 2

Joel 2:19-30