Job 7:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbati mo dubulẹ̀, emi wipe, nigbawo ni emi o dide, ti oru yio si kọja? o si tó fun mi lati yi sihin yi sọhun titi yio fi di afẹmọ́jumọ.

Job 7

Job 7:1-12