Job 6:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE) JOBU si dahùn o si wipe, A! a ba le iwọ̀n ibinujẹ mi ninu òṣuwọn, ki a si le igbe ọ̀fọ mi le ori òṣuwọn