Job 42:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati ni gbogbo ilẹ na, a kò ri obinrin ti o li ẹwa bi ọmọbinrin Jobu; baba wọn si pinlẹ fun wọn ninu awọn arakunrin wọn.

Job 42

Job 42:5-17