Job 39:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IWỌ mọ̀ akoko igbati awọn ewurẹ ori apata ibimọ, iwọ si le ikiyesi igba ti abo-agbọnrin ibimọ?

2. Iwọ le ika iye oṣu ti nwọn npé, iwọ si mọ̀ àkoko igba ti nwọn ibi?

Job 39