Job 37:21 Yorùbá Bibeli (YCE)

Sibẹ nisisiyi enia kò ri imọlẹ ti ndán ninu awọsanma, ṣugbọn afẹfẹ kọja, a si gbá wọn mọ́.

Job 37

Job 37:19-24