Job 34:36-37 Yorùbá Bibeli (YCE)

36. Ifẹ mi ni ki a dán Jobu wò de opin, nitori idahùn rẹ̀ nipa ọ̀na enia buburu;

37. Nitoripe o fi iṣọtẹ kún ẹ̀ṣẹ rẹ̀, o papẹ́ li awujọ wa, o si sọ ọ̀rọ pupọ si Ọlọrun.

Job 34