Job 30:14-16 Yorùbá Bibeli (YCE)

14. Nwọn de si mi bi yiya omi gburu, ni ariwo nla ni nwọn ko ara wọn kátì si mi.

15. Ẹ̀ru nla yipada bà mi, nwọn lepa ọkàn mi bi ẹfùfù, alafia mi si kọja lọ bi awọsanma.

16. Ati nisisiyi ọkàn mi si dà jade si mi, ọjọ ipọnju dì mi mu.

Job 30