Job 3:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE) LẸHIN eyi ni Jobu yanu o si fi ọjọ ibi rẹ̀ ré. Jobu sọ, o si wipe, Ki ọjọ ti a bi mi ki o di igbagbe, ati oru