Job 25:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBANA ni Bildadi, ara Ṣua, dahùn wipe,

2. Ijọba ati ẹ̀ru mbẹ lọdọ rẹ̀, on ni iṣe ilaja ni ibi gigagiga rẹ̀.

3. Awọn ọmọ-ogun rẹ̀ ha ni iye bi, tabi ara tani imọlẹ rẹ̀ kò mọ́ si?

Job 25