Job 21:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. SUGBỌN Jobu dahùn, o si wipe,

2. Ẹ tẹti silẹ dẹdẹ si ohùn mi, ki eyi ki o jasi itunu nyin.

3. Ẹ jọwọ mi ki emi sọ̀rọ, lẹhin igbati mo ba sọ tan, iwọ ma fi ṣẹsin nṣo.

Job 21