Job 18:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kì yio ni ọmọ bibikunrin tabi ajọbi-kunrin ninu awọn enia rẹ̀, bẹ̃ni kò si ẹnikan ti o kù ninu agbo ile rẹ̀.

Job 18

Job 18:10-21