Job 18:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. NIGBANA ni Bildadi, ara Ṣua, dahùn o si wipe,

2. Nigba wo li ẹnyin o to fi idi ọ̀rọ tì; ẹ rò o, nigbẹhin rẹ̀ li awa o to ma sọ.

3. Nitori kili a ṣe nkà wa si bi ẹranko, ti a si nkà wa si bi ẹni ẹ̀gan li oju nyin!

Job 18