Job 13:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Wò o, oju mi ti ri gbogbo eyi ri, eti mi si gbọ́ o si ti ye e.

2. Ohun ti ẹnyin mọ̀, emi mọ̀ pẹlu, emi kì iṣe ọmọ-ẹhin nyin.

3. Nitotọ emi o ba Olodumare sọ̀rọ, emi si nfẹ ba Ọlọrun sọ asọye.

Job 13