Job 12:20-22 Yorùbá Bibeli (YCE)

20. O mu ọ̀rọ-ẹnu ẹni-igbẹkẹle kuro, o si ra awọn àgbàgbà ni iye.

21. O bù ẹ̀gan lu awọn ọmọ-alade, o si tú àmure awọn alagbara.

22. O hudi ohun ti o sigbẹ jade lati inu òkunkun wá, o si mu ojiji ikú jade wá sinu imọlẹ̀.

Job 12