Job 12:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) JOBU si dahùn o si wipe, Kò si ani-ani nibẹ̀, ṣugbọn ẹnyin li awọn enia na, ọgbọ́n yio si kú pẹlu nyin.