Joṣ 8:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Joṣua si dide, ati gbogbo awọn ọmọ-ogun, lati gòke lọ si Ai: Joṣua si yàn ẹgba mẹdogun, alagbara akọni, o si rán wọn lo li oru.

Joṣ 8

Joṣ 8:1-10