Joṣ 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti awọn ara Kenaani ati gbogbo awọn ara ilẹ na yio gbọ́, nwọn o si yi wa ká, nwọn o si ke orukọ wa kuro li aiye: kini iwọ o ha ṣe fun orukọ nla rẹ?

Joṣ 7

Joṣ 7:1-12