Joṣ 7:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn enia Ai pa enia mẹrindilogoji ninu wọn: nwọn si lepa wọn lati ẹnubode titi dé Ṣebarimu, nwọn si pa wọn bi nwọn ti nsọkalẹ: àiya awọn enia na já, o si di omi.

Joṣ 7

Joṣ 7:4-9