Joṣ 4:11 Yorùbá Bibeli (YCE)

O si ṣe, nigbati gbogbo awọn enia na rekọja tán, ni apoti OLUWA rekọja, ati awọn alufa, li oju awọn enia.

Joṣ 4

Joṣ 4:2-14