Joṣ 24:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Emi si mú Abrahamu baba nyin lati ìha keji Odò na wá, mo si ṣe amọ̀na rẹ̀ là gbogbo ilẹ Kenaani já, mo si sọ irú-ọmọ rẹ̀ di pipọ̀, mo si fun u ni Isaaki.

Joṣ 24

Joṣ 24:1-6