Joṣ 24:18 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA si lé gbogbo awọn enia na jade kuro niwaju wa, ani awọn Amori ti ngbé ilẹ na: nitorina li awa pẹlu o ṣe ma sìn OLUWA; nitori on li Ọlọrun wa.

Joṣ 24

Joṣ 24:8-28