Joṣ 23:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitoriti OLUWA ti lé awọn orilẹ-ède nla ati alagbara kuro niwaju nyin; ṣugbọn bi o ṣe ti nyin ni, kò sí ọkunrin kan ti o ti iduro niwaju nyin titi di oni.

Joṣ 23

Joṣ 23:1-16